Grays Beach Litter Pick_Feb 2016Ile iṣẹ ore-aanu fun Environmental, Thames 21 ti yan Grays Beach ni agbegbe Thames fun itọju idọọti ati pe wọn wa ẹniti o fẹ ṣiṣẹ laigba owo ni adugbo lati ran wọn lọwọ.

Emma Harrington, Oluṣakoso Idagbasoke sọ fun Grays Riverside Community Big Local ni pe wọn wa eniyan ogoji (40) ti wọn ma ṣiṣẹ laigba owo fun wakati mẹta (3). Thurrock Yacht Club ma jẹ ki wọn lo ohun elo wọn.

Bi o ba nifẹ lati ṣe iranlọwọ, jọwọ fọwọsi fọọmu yi lati forukọsilẹ

[contact-form-7 404 "Not Found"]